explain-icon

Àlàyé

Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pé ẹni tí o ba lọ onigbese lára, tabi ti o ba a din gbese rẹ ku, ẹsan rẹ ni pe: Ọlọhun maa fi i sábẹ́ ibòji Itẹ-ọla Rẹ̀ ni Ọjọ́ Àjíǹde ti oorun maa sunmọ orí àwọn ẹrú ti ooru rẹ si maa lágbára, Ẹni kankan ko nii ri ibòji àyàfi ẹni tí Ọlọhun ba fi si abẹ ibòji.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Ọla ti n bẹ fun ṣíṣe idẹkun fun awọn ẹru Ọlọhun ti ọla Rẹ ga, ati pe o wa ninu awọn okùnfà ti o maa la èèyàn kuro nibi ibẹru Ọjọ́ Àjíǹde.
  • Ẹsan maa wa latara iran iṣẹ.