- AL-MUHKAM ninu awọn aaya Kuraani ni: Ohun ti itumọ rẹ ko pamọ, AL-MUTASHAABIH ni: Ohun ti o ni ju itumọ kan lọ, ti o si bukaata si ìwòye ati agbọye.
- Ìkìlọ̀ kuro nibi dídarapọ̀ mọ́ àwọn ti n gbúnrí kuro nibi ododo, ati awọn oni adadaalẹ, ati awọn ti maa n da iruju silẹ lati ṣi àwọn èèyàn lọ́nà ati lati ko iyèméjì ba wọn.
- O n bẹ nibi pipari aaya naa pẹ̀lú gbólóhùn Rẹ pe: { Kò sí ẹni t’ó ń lo ìrántí àyàfi àwọn onílàákàyè} ìdọ́gbọ́nbú awọn ti wọn gbúnrí kuro nibi òdodo, ati ẹyìn fun awọn ti ẹsẹ wọn rinlẹ ninu imọ, o n túmọ̀ si pe: Ẹni ti ko ba ti lo ìrántí, ti o wa tẹle ifẹ-inu rẹ, onítọ̀hún ko si ninu awọn onilaakaye.
- Itẹle nnkan ti o ruju maa n fa igbunri ọkàn kuro nibi òdodo.
- Dandan ni ki a da àwọn aaya to ruju ti a le ma gbọ itumọ wọn yé pada si awọn aaya ti ko ruju.
- Ọlọhun ṣe apá kan ninu Kuraani ni nǹkan ti ko ruju, O si ṣe apá kan ni ohun ti o ruju; ki o maa jẹ àdánwò fun awọn èèyàn ki awọn onigbagbọ le yatọ si awọn ẹni anù.
- O n bẹ nibi wíwà nnkan ti o ruju nínú Kuraani: Àfihàn ọla àwọn onimimọ lori awọn to yatọ si wọn, ati mímú làákàyè mọ̀ nipa ikudiẹ-kaato rẹ; ki o le jupa-jusẹ silẹ fun Ẹni ti O da a, ki o si jẹwọ ikagara rẹ.
- Ọla ti n bẹ fun ki ẹsẹ o rinlẹ ninu imọ ati ìjẹ́dandan iduroṣinṣin nibẹ.
- Ọrọ meji ni àwọn to n ṣàlàyé itumọ Kuraani sọ nipa diduro nibi gbólóhùn {ALLOOHU} nibi ọ̀rọ̀ Rẹ ti O sọ pe {WA MAA YAH’LAMU TAHWIILAHUU ILLAA ALLOOHU WAR-RAASIKHUUNA FIL IL’M}, ẹni tí ó bá dúró lórí {ALLOOHU}, a jẹ́ wipe AT-TAHWIIL maa túmọ̀ si mímọ pàápàá nǹkan ati ohun ti ko si bi eeyan ṣe fẹ mọ̀ ọ́n bii ọ̀rọ̀ nipa ẹ̀mí, ati igba ti ayé maa parẹ́, ninu awọn nnkan ti o ṣe pe Ọlọhun nìkan ni O ni imọ nipa rẹ, àwọn ti ẹsẹ wọn rinlẹ ninu imọ maa gba a gbọ́, wọn si maa fa imọ nipa pàápàá rẹ le Ọlọhun lọ́wọ́, wọn si maa jupa-jusẹ silẹ, ṣùgbọ́n ẹni tí ko ba duro lórí gbólóhùn {ALLOOHU}, AT-TAHWIIL maa túmọ̀ si itumọ ati àlàyé, o maa wa jẹ pe Ọlọhun mọ̀ ọ́n, àwọn ti ẹsẹ wọn rinlẹ ninu imọ naa si mọ̀ ọ́n, wọn maa wa gba a gbọ́, wọn si maa da a pada sibi eyi ti ko ruju.
-
- English - إنجليزي - English
- العربية - عربي - Arabic
- español - إسباني - Spanish
- português - برتغالي - Portuguese
- Français - فرنسي - French
- Русский - روسي - Russian
- اردو - أردو - Urdu
- Deutsch - ألماني - German
- Shqip - ألباني - Albanian
- বাংলা - بنغالي - Bengali
- ဗမာ - بورمي - Burmese
- bosanski - بوسني - Bosnian
- தமிழ் - تاميلي - Tamil
- ไทย - تايلندي - Thai
- සිංහල - سنهالي - Sinhala
- Kiswahili - سواحيلي - Swahili
- svenska - سويدي - Swedish
- Tiếng Việt - فيتنامي - Vietnamese
- മലയാളം - مليالم - Malayalam
- हिन्दी - هندي - Hindi
- Hausa - هوسا - Hausa
- Èdè Yorùbá - يوربا - Yoruba
- فارسی - فارسي - Persian
- Türkçe - تركي - Turkish
- 中文 - صيني - Chinese
- Bahasa Indonesia - إندونيسي - Indonesian
- Wikang Tagalog - فلبيني تجالوج - Tagalog
- پښتو - بشتو - Pashto
- አማርኛ - أمهري - Amharic
- ئۇيغۇرچە - أيغوري - Uyghur
- తెలుగు - تلقو - Telugu
- 日本語 - ياباني - Japanese
- Kurdî - كردي - Kurdish
- Nederlands - هولندي - Dutch
- čeština - تشيكي - Czech
- ગુજરાતી - غوجاراتية
- অসমীয়া - آسامي - Assamese
- azərbaycanca - أذري - Azerbaijani
- Ўзбек - أوزبكي - Uzbek
- فلبيني مرناو - فلبيني مرناو - فلبيني مرناو
- براهوئي - براهوئي - براهوئي
- български - بلغاري - Bulgarian
- polski - بولندي - Polish
- татар теле - تتاري - Tatar
- română - روماني - Romanian
- isiZulu - زولو - Zulu
- سنڌي - سندي - Sindhi
- нохчийн мотт - شيشاني - Chechen
- Soomaali - صومالي - Somali
- тоҷикӣ - طاجيكي - Tajik
- غجري - غجري - غجري
- Pulaar - فلاتي - فلاتي
- Pulaar - فولاني - Fula
- قمري - قمري - قمري
- कश्मीरी - كشميري - Kashmiri
- 한국어 - كوري - Korean
- македонски - مقدوني - Macedonian
- bahasa Melayu - ملايو - Malay
- magyar - هنجاري مجري - Hungarian
- ελληνικά - يوناني - Greek
- қазақ тілі - كازاخي - Kazakh
- עברית - عبري - Hebrew
- dansk - دنماركي - Danish
- Tamazight - أمازيغي - Tamazight
- أنكو - أنكو - أنكو
- Luganda - لوغندي - Ganda
- ትግርኛ - تجريني - Tigrinya
- غموقي - غموقي - غموقي
- Кыргызча - قرغيزي - Кyrgyz
- नेपाली - نيبالي - Nepali
- italiano - إيطالي - Italian
- українська - أوكراني - Ukrainian
- eesti - إستوني - Estonian
- suomi - فنلندي - Finnish
- Адыгэбзэ - شركسي - Адыгэбзэ
- Norwegian - نرويجي - Norwegian
- latviešu - لاتفي - Latvian
- slovenščina - سلوفيني - Slovene
- монгол - منغولي - Mongolian
- íslenska - آيسلندي - Icelandic
- ქართული - جورجي - Georgian
- tamashaq - طارقي - tamashaq
- ދިވެހި - ديفهي - Dhivehi
- Հայերէն - أرميني - Armenian
- slovenčina - سلوفاكي - Slovak
- Afrikaans - أفريقاني - Afrikaans
- Türkmençe - تركماني - Turkmen
- башҡорт теле - بلوشي - Bashkir
- afaan oromoo - أورومو - Oromoo
- ភាសាខ្មែរ - خميرية - Khmer
- ಕನ್ನಡ - كنادي - Kannada
- Bassa - الباسا
- Lingala - لينغالا
- lietuvių - ليتواني - Lithuanian
- bamanankan - بامبارا - Bambara
- Soninke - سوننكي - Soninke
- Malagasy - ملاغاشي - Malagasy
- Mandinka - مندنكا - Mandinka
- Sängö - سانجو
- Wollof - ولوف - Wolof
- Cham - تشامي - Cham
- Српски - صربي - Serbian
- Afaraf - عفري - Afar
- Kinyarwanda - كينيارواندا - Kinyarwanda
- Jóola - جوالا
- Bi zimanê Kurdî - كردي كرمنجي - Bi zimanê Kurdî
- Akan - أكاني - Akan
- Chichewa - شيشيوا - Nyanja
- авар мацӀ - أوارية
- isiXhosa - خوسي
- मराठी - ماراثي - Marathi
- ГӀалгӀай - إنغوشي - ГӀалгӀай
- Mõõré - موري - Mõõré
- Maguindanao - فلبيني مقندناو - Maguindanaon
- Dagbani - دغباني
- Yao - ياؤو
- Ikirundi - كيروندي
- Bisaya - بيسايا
- Ruáingga - روهينجي
- فارسی دری - دري
- Sesotho - سوتي
- ਪੰਜਾਬੀ - بنجابي
- créole - كريولي
- ພາສາລາວ - لاو
- Qhichwa simi - كيشوا
- hrvatski - كرواتي
- aymar aru - أيمري
- ଓଡ଼ିଆ - أوديا
- Igbo - إيجبو
- Fɔ̀ngbè - فون
- Mɛnde - مندي
