explain-icon

Àlàyé

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n ṣàlàyé pe alaigbagbọ ti o ba gba Isilaamu wọn maa san an lẹsan lori nnkan ti o n ṣe ni asiko aimọkan ṣíwájú gbigba Isilaamu rẹ ninu awọn iṣẹ oloore bii saara ṣíṣe ati bibọkun kúrò lọrun ẹru tabi siso ibi papọ.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Dajudaju awọn daadaa ti alaigbagbọ ba ṣe wọn ko nii san an lẹsan lori wọn ni ọrun ti o ba ku lori ṣíṣe aigbagbọ rẹ.