Anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá rẹ máa ba fún wa niro pé tí wan ba gbé òkú kalẹ lórí ibùsùn, tí awàn eniyan l'ọkunrin sí gbé sórí ọrùn wan , tí o ba ṣepe ẹniire ni yóò sọ pé: etimi síwájú sí bí idẹra tí o wa níwájú rẹ, tí kí baa se eniire yóò parí wo pẹlu òunh tí arà kọ pé : ìparun tí dé ba òun nibo ni wan ngbé òunh lọ yì ?! Nitori ìyá tí o tiri ni iwájú rẹ, gbogbo nkán ni yóò gbọ òunh rẹ ayaafi ènìyàn, tí ènìyàn ba gbọ kò bà daku lẹkan náà latara lilagbara nkán to fí etí ará rẹ gbọ.