explain-icon

Àlàyé

Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pé: Ti Ọlọhun ba kádàrá fun ẹrú kan pe ki o kú sí ilẹ̀ kan ti ko si si nibẹ; O maa jẹ ki o ni bukaata si i, yoo waa wa si ibẹ, wọn si maa gba ẹ̀mí rẹ nibẹ.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Hadiisi naa n jẹrii si òdodo ọ̀rọ̀ Ọlọhun ti O lágbára ti O gbọnngbọn ti O sọ pe: {Ẹ̀mí kan kò sì mọ ilẹ̀ wo l’ó máa kú sí}.