logo
  • Ilé
  • Àwọn Ìsọ̀rí pàtàkì arrow

    Àwọn Ìsọ̀rí pàtàkì

    • Kuraani Alapọn-ọnle ati àwọn imọ rẹ
    • Hadiisi ati awọn imọ rẹ
    • Adisọkan
    • Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ
    • Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ
    • Ipepe si oju ọna Ọlọhun ati pipaṣẹ dáadáa ati kikọ ìwà ibajẹ
    • Itan ìgbésí ayé
  • Nipa iṣẹ akanṣe naa
  • portal_of_developers
  • Kàn sí wa mail
Kàn sí wa mail
earth Èdè Yorùbá arrow

choose_language

share_hadeeth

available_translations:

  1. Ilé
  2. Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ
  3. Awọn ẹkọ ofin sharia
  4. Awọn ẹkọ jijẹ ati mimu
  5. Hadiisi
Lati ọdọ Ibnu Umar- ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji- dajudaju ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: “Ti ẹnikẹni ninu yẹn ba fẹ jẹun ki o yaa jẹun pẹlu ọwọ ọtun rẹ, ti o ba si fẹ mu ki o yaa mu pẹlu ọwọ ọtun rẹ, dajudaju Shaitan maa n jẹun pẹlu ọwọ osi rẹ, o si maa n mu pẹlu ọwọ osi rẹ”. O ni alaafia - Muslim gba a wa
  • earth
  • English
  • čeština
  • Kinyarwanda
  • Soomaali
  • العربية
  • español
  • choose_language

    • português
    • Русский
    • اردو
    • Deutsch
    • Shqip
    • বাংলা
    • ဗမာ
    • bosanski
    • தமிழ்
    • ไทย
    • සිංහල
    • Kiswahili
    • svenska
    • Tiếng Việt
    • മലയാളം
    • हिन्दी
    • Hausa
    • فارسی
    • Türkçe
    • 中文
    • Bahasa Indonesia
    • Wikang Tagalog
    • پښتو
    • አማርኛ
    • ئۇيغۇرچە
    • తెలుగు
    • 日本語
    • Kurdî
    • Nederlands
    • ગુજરાતી
    • অসমীয়া
    • тоҷикӣ
    • Кыргызча
    • नेपाली
    • lietuvių
    • Српски
    • فارسی دری
explain-icon

Àlàyé

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n pàṣẹ pe ki Musulumi maa jẹ ki o si maa mu pẹlu ọwọ rẹ ọtun, o si kọ kuro nibi jijẹ ati mimu pẹlu ọwọ osi; ìyẹn rí bẹ́ẹ̀ nítorí pe Shaitan maa n jẹ o si maa n mu pẹlu rẹ.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Kikọ kuro nibi fifi ara wé Shaitan pẹlu jijẹ tabi mimu pẹlu ọwọ osi.
explain-icon

Àwọn ìsọ̀rí

  1. Ilé
  2. Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ
  3. Awọn ẹkọ ofin sharia
  4. Awọn ẹkọ jijẹ ati mimu
  5. Hadiisi
explain-icon

Àlékún

  • Ẹnikẹni ninu yin o gbọdọ fi ọwọ ọtun rẹ mu nkan ọmọkunrin rẹ nigba ti o ba n tọ, ko si gbọdọ fi ọwọ rẹ ọtun ṣe imọra nibi igbọnsẹ, ko si gbọdọ fẹ atẹgun si inu ife imumi
  • Irẹ ọmọdekunrin yii, darukọ Ọlọhun, ki o si jẹun pẹlu ọwọ ọtun rẹ, ki o si tun jẹ ninu nkan ti o sunmọ ọ
  • Dajudaju arakunrin kan jẹun lọdọ ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- pẹlu ọwọ osi rẹ, o sọ pe: "Jẹun pẹlu ọwọ ọtun rẹ", o sọ pe: Mi ko ni ikapa, o sọ pe: "O ò sì nii ní ikapa
  • “Dájúdájú Ọlọhun maa n yọnu si ẹrú ti o ba jẹun ti o wa dúpẹ́ lori rẹ, tabi ti o mu ti o wa dupẹ lórí rẹ”
logo

Ìwé agbedegbẹyọ fun awọn hadiisi Anọbi ti a tu si èdè mìíràn

Iṣẹ́ àkànṣe ti o n rí si pípèsè àwọn àlàyé ti o rọrùn ati awọn ìtumọ̀ ti o hàn fún àwọn hadiisi Anọbi ti o ni àlàáfíà

Àwọn Ìsọ̀rí pàtàkì

  • Kuraani Alapọn-ọnle ati àwọn imọ rẹ
  • Hadiisi ati awọn imọ rẹ
  • Adisọkan
  • Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ
  • Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ
  • Ipepe si oju ọna Ọlọhun ati pipaṣẹ dáadáa ati kikọ ìwà ibajẹ
  • Itan ìgbésí ayé

Important Websites

  • Bayan Al islam
  • The holy quran encyclopedia
  • Developers API
logo