explain-icon

Àlàyé

Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – kọ fifa apakan irun ori ati fifi apakan silẹ. Ati pe kikọ naa ko gbogbo ọmọde ọkunrin ati agbalagba ọkunrin sinu, ṣugbọn ọmọbinrin ko tọ fun un ki o fa irun ori rẹ.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Nini akolekan ofin Isilāmu si irisi ọmọnìyàn.