explain-icon

Àlàyé

Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pé olofofoo ti n gbe ọ̀rọ̀ kiri láàrin àwọn èèyàn láti da àárín wọn rú, pe iru ẹni bẹẹ ni ẹtọ si ìjìyà pe ko nii wọ alujanna.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Òfófó wa ninu awọn ẹṣẹ ńlá.
  • Kikọ ofofo ṣíṣe; tori ibajẹ ati ìnira laarin ẹni kọọkan ati awọn janmọọn ti o wa ninu ẹ.