explain-icon

Àlàyé

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe dajudaju ọjọ igbende ko nii to titi ti arakunrin maa fi kọja nibi saare ti yoo si maa gbero lati jẹ oku dipo rẹ, idi ni ibẹru rẹ lori ara rẹ nibi lilọ ẹsin rẹ pẹlu ibori ibajẹ ati awọn onibajẹ, ati hihan awọn fitina ati awọn ẹṣẹ ati awọn ibajẹ.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Itọka pẹlu hihan awọn ẹṣẹ ati awọn wahala ni igbẹyin aye.
  • Ṣisẹnilojukokoro lori iṣọra ati igbaradi fun iku pẹlu igbagbọ ati awọn iṣẹ oloore, ati jijina si awọn aaye wahala ati adanwo.