explain-icon

Àlàyé

Ninu ìlànà Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ni pe kii da lọfinda padà, o si maa n gbà á; torí pé o fúyẹ́ ni gbígbé, òórùn rẹ si dára.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • A fẹ ki a gba ẹbun lọfinda; torí pé ko si ipese kan kan fun gbígbé e, ko si si ìrègún nibi gbigba a.
  • Pípé ati dídára ìwà Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- nibi pe kii da lọ́fíńdà pada, ati gbigba ẹ̀bùn lọ́wọ́ ẹni tí ó bá fún un.
  • Ṣiṣenilojukokoro lori lílo lọ́fíńdà.
explain-icon

Àlékún