explain-icon

Àlàyé

Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣọ wa lara kuro nibi mimu ìpalára wọlé tọ Musulumi, tabi fifi ìnira kan an nibi èyíkéyìí àlámọ̀rí; yálà nibi ẹ̀mí rẹ ni, tabi dúkìá rẹ, tabi ará-ilé rẹ. Ẹni tí ó bá wa ṣe iyẹn, Ọlọhun maa san an ni ẹsan, O si maa fi ìyà jẹ ẹ ninu iran iṣẹ ti o ṣe.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Ṣíṣe kiko ìpalára ati ìnira ba Musulumi ni eewọ.
  • Ọlọhun maa n ba àwọn ẹrú Rẹ gba ẹsan.
explain-icon

Àlékún