Lati ọdọ iya awọn olugbagbọ ododo, A'isha ki Ọlọhun bawa yọnu sì i, o sọ bayi pe: Mi o ri ki anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba - ki o fi gbogbo ara rẹrin titi ti maa fì wá rí bèlúbèlú rẹ̀, ṣugbọn Anọbi aa máa rẹrin musẹ. O ni alaafia - Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
explain-icon

Àlàyé

Ki Ọlọhun bá wa yọnu si A'isha, Oun ló fún wa niro pe Anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - Kii mọn fi gbogbo ara rẹrin ti a fi waa rí belubelu rẹ, (belubelu ni ẹran ti o so mọ oke ọ̀nà ọ̀fun) ṣugbọn Anọbi aa maa rẹrin musẹ.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Òjíṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - itumusẹ ni ẹrin rẹ nigbati o bá yọnu tabi ti nkankan ba wun un.
  • Alufa Ọmọ Hajar so fún wa pé : mi o ri ko fi gbogbo ara rẹ rin , ni a bala erin , ti yóò fi gbogbo enu ati ara rerin .
  • Ọpọlọpọ ẹrin, ati igbe ohun soke lati rẹ́rìn keekee kò sí ninu iroyin awọn ẹni rere.
  • Ọpọlọpọ ẹrin aa máa gba ọwọ àti ìbẹ̀rù kuro lara eniyan laarin awọn ọmọ ìyá rẹ.
explain-icon

Àwọn ìsọ̀rí

explain-icon

Àlékún