explain-icon

Àlàyé

Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ṣe alaye wipe dajudaju ipilẹ ninu irun ni iduro, ayaafi ni igba ti ko ba si ikapa, nigba naa yio ki i ni ẹnití o jokoo, ti ko ba tun ni ikapa kiki irun ni ẹni ti o jokoo, o le ki i ni ifẹgbẹlelẹ.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Wọn o le yọnda irun lopin igba ti laakaye ba ṣi wa, nigba naa kikuro ni ipo kan si ipo miran a maa ṣẹlẹ ni ibamu si ikapa.
  • Irọrun Isilaamu n bẹ nibi pe ẹrú yio maa ṣe eyikeyii ti o ba ti rọ ọ lọrun ninu ijọsin.
explain-icon

Àlékún