explain-icon

Àlàyé

Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹniti o pe julọ ni iwa, o si tun gba iwájú nibi gbogbo iwa ati nkan daadaa, nibi ọrọ to daa, ati ṣiṣe daadaa, ati titu oju ka, ati mimu suta kuro ati nini atemọra rẹ lati ọdọ ẹlòmíràn.

explain-icon

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  • Pipe iwa Anabi (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a).
  • Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – ni awokọṣe ti o pe nibi iwa daadaa.
  • Ṣiṣenilojukokoro lori wiwo Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – kọṣe nibi iwa daadaa rẹ.